Oríkì Ìlú Ọ̀yọ́: Eulogy of Ọ̀yọ́ Town

0
174
Oríkì Ìlú Ọ̀yọ́: Eulogy of Ọ̀yọ́ Town

ORÍKÌ ÌLÚ Ọ̀YỌ́
Ọ̀yọ́ ọmọ Aláàfin
Òjò pa ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ ma dẹ̀ ọmọ Àtìbà.
Ọmọ Ò-kólówó pé kó gbowó
Ò-kọ́wọ̀fà pé kó fọfàá lẹ̀
À ṣe kó lè ba à dìjà
À ṣe kò lè ba à daápọn ni?
K’ọmọ Ọba ‘Ládéyẹrí lè rí nǹkan ṣèjẹ……

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here