Oríkì Ìlú Ẹ̀gbá (Eulogy of Ẹ̀gbá Land)

Kò s’óhun tí wọ́n ń ṣe ní Mẹ́kà,
Táwa kì í ṣe l’Ẹ́gbàá ti wa.
Wọ́n ń mu’mi sẹ́mí-sẹmì ní Mẹ́kà,
Àwa ń mu’mi odò Ògùn l’Ẹ́gbàá.
Wọ́n ń gàràfá ní Mẹ́kà,
Àwa ń g’òkè Olúmọ l’Ẹ́gbàá ti wa.

Watch the video for full lyrics

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here