Iṣẹ́ ni òògùn ìṣẹ́
Múra sí iṣẹ́ rẹ, ọ̀rẹ́ mi
Iṣẹ́ ni a fi ń dẹni gíga
Bí a kò bá rẹ́ni fi ẹ̀yìn tì
Bí ọ̀lẹ là á rí
Bí a kò bá rẹ́ni gbẹ́kẹ̀lé
A tẹra mọ́ṣẹ́ ẹni
Ìyá rẹ lè lówó lọ́wọ́
Bàbá rẹ sì lè lẹ́ṣin léèkàn
Bí o bá gbójú lé wọn,
O tẹ́tán ni mo sọ fún ọ…

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here