Àjọ Ìṣọ̀kan Àgbáyé ṣe àgbékalẹ̀ ayẹyẹ àyájọ́ èdè abínibí ní ọdún 1999. Gbogbo ọjọ́ Kọkànlélógún oṣù kejì (February 21) ni wọ́n là kalẹ̀ fún wa láti máa ṣe ìrántí ayẹyẹ yìí. Èyí rí bẹ́ẹ̀ láti lè mú ìlọsíwájú bá onírúurú àṣà àti èdè tó wà láwùjọ ẹ̀dá.
Ayẹyẹ yìí ló ń mú ìlọsíwájú bá ìdáàbòbò onírúurú èdè lágbàáyé.

Èdè wa làṣà wa. Ẹ jẹ́ kí á náání rẹ̀.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here