About Us

Àbáláyé Nàìjíríà jẹ́ ètò tí a ṣe àgbékalẹ̀ láti kọ́ àwọn ọmọ Nàìjíríà (Yorùbá) ní pàtàkì ẹ̀kọ́ èdè, àṣà àti ìṣe àjogúnbá Yorùbá nípa ṣíṣe àmúlò Òwe, Àlọ́-àpamọ̀, Àlọ́-àpagbè, Orin, Àkànlò èdè, Ìtàn, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

 

Do you want to partner, advertise or help us to improve better, you can shoot us a message by filling the form below.