Creation Story According to Yorùbá mythology

Ọ̀rọ̀ kì í gba àárọ̀, Kí á fi alẹ́ sọ ọ́; A díá fún Òkòkó nìyẹ̀lẹ̀ Tí yóò bá ni túlẹ̀ yí wò. Nígbà tí Olódùmarè kọ́ ṣe...

Alénibáre L’ọmọ Ará Ayé

B'ágbọ́n bá fẹ́ șoro; A k'ìdí bọlé. B'áláàmù ó bàá șoro; A k'ìdí bàlàpà. Bí Șàngó Olúkòso ó bàá șoro; A máa kọ mọ̀nà l'ójú ọ̀run. Abéjidé Ìgè Àdùbí. Mo șetán,...

Yoruba Quiz Competition 2018 (Pictures)

The Yoruba Quiz Competition 2018 organized by Abalaye Nigeria in collaboration with Yoruba Youth Initiatives witnessed a large turn-up from participating schools and the...
June 12 Democracy Day

JUNE 12, 1993 (Ẹ jẹ́ ká níra wa létí)

Ọjọ́ náà rèé bí àná. Ọjọ́ tí 'ò yé máa ránni bí ooju. Ọjọ́ kan gbòógì; T'ọ́mọ Nàìjá f'ohùn șọ̀kan. Ọjọ́ tá a dìbò bó ti tọ́. Ọjọ́ kan...
Yoruba Birthday Poetry

ỌJỌ́-ÌBÍ Ẹ̀DÁ

Ọjọ́ ńlá l'ọ̀jọ́ a bíni sáyé. Ọjọ́ tá a ké wẹ́ẹ̀ wẹ́ẹ̀, Ọjọ́ kan kùù tó yakin ni. Ọjọ́ a kọ́kọ́ mumi ayé pàá, Ọjọ́ kan gbòógì, Tí í...
Yoruba Poetry

OJÚ-Ọ̀NÀ ÀȘẸYỌRÍ (Yoruba Poetry)

Onírúurú ìpènijà; Ọ̀kan-'ò-jọ̀kan ìdààmú, Oníranǹran aápọn ló forímù; Farasin s'ójú-ọ̀nà aṣeyege. Ìtàkùn ìjákulẹ̀ ń bẹ níbẹ̀; T'òun t'àbàtà èérí. Ká tó k'ógo já l'ókè-erùpẹ̀, Dandan ni ká f'ara yẹ́gbin. Háà!!! Ojú ti rí...
Yoruba Poetry

ỌLỌ́RUN NI (Yoruba Poetry)

Fùlengefùlenge àkàrà; Kò kúkú sé lẹ́yìn erèé láyé. Gàlègàlè ẹja l'álẹ̀-odò, Kò kúkú sé lẹ́yìn omi. Igba ọgbà, Tó dúró gbágbáágbá; Ó dá mi lójú gbamgba, Igi ló wà lẹ́yìn ọgbà, L'ọgbà...
irin ajo eda laye poem

Ìrìn-àjò ẹ̀dá láyé

Yéké, l'ó yé Olúwa Ọba. Ìrìnkèrindò ọmọ ènìyàn; Kedere l'ó hàn sÉdùmàrè. K'á sáré sáré; Nítorí ọsàn. K'á pọ̀șẹ̀șẹ̀ pọ̀șẹ̀șẹ̀; Nítorí àtimusàn. Șáká l'ó dájú; Ọba-òkè ní í fúnni l'ọ́sàn t'ó dùn...

Oríkì Ìlú Ẹ̀gbá (Eulogy of Ẹ̀gbá Land)

Oríkì Ìlú Ẹ̀gbá (Eulogy of Ẹ̀gbá Land) Kò s'óhun tí wọ́n ń ṣe ní Mẹ́kà, Táwa kì í ṣe l'Ẹ́gbàá ti wa. Wọ́n ń mu'mi sẹ́mí-sẹmì ní...
Abd Olorin (Yoruba Musical Alphabet)

Video: ABD Olórin (Yorùbá Musical Alphabet)

Watch the Yorùbá Musical Alphabet on AbalayeTV and Do Not forget to subscribe. https://www.youtube.com/watch?v=EwpTxPe0hms

Most Commented

abalaye.com is processing...

Subscribe to our newsletter

Want to be notified when our article is published? Enter your email address and name below to be the first to know.